Bawo! Emi ni Rana Sabiha!
4
Pẹlẹ o! Orukọ mi ni Rana Sabiha. Mo ti ni fẹ ọkọ ati pe Mo ni ọmọkunrin.mo le sọ èdè Gẹẹsi diẹ.Turkish ni ede abinibi mi. Mo jẹ ọmọ ọdun 20 ati pe món gbé ni Tọki a bí ni Ilu Istanbul ati pe Mo ngbe pupọ julọ ni Ilu Istanbul. awọn eniyan ti o wa ni Tọki ti o ni itara ati pe wọn gba eniyan móra gán. Pẹlupẹlu, awọn aye itan ni Ilu Istanbul lẹwa gán. yoo di irin-ajo ti ko ṣe gbàgbé.
Translated by:
5
8
Hi Rana Sabiha! Istanbul is a very nice city,I've been there. :) I would like to learn Turkish language. I already know a very few words,some basic but I would like to know how to speak in Turkish language.