3
3 replies
|
+1
yor

Pẹlẹ o, orukọ mi ni Christophe, baba mi jẹ Faranse ati iya mi jẹ ara Serbia. Nigbati mo jẹ ọmọde Emi ko fẹ lati kọ ẹkọ Serbia; Emi yoo fẹ lati ṣe atunṣe. Ọmọ ọdún márùnléláàádọ́ta [55] ni mí, mo sì ti ń kẹ́kọ̀ọ́ Serbian ní wákàtí kan lọ́sẹ̀ fún ohun tó lé lọ́dún kan.

Translated by:

5
5
yor
|

Pẹlẹ o, orukọ mi ni olamide ati pe mo duro pẹlu obi mi ni èko, Nigeria. Ede abinibi mi ni Yoruba bi o tile je pe mo n so èdè gẹ̀ẹ́sì daadaa, ati pe Emi yoo fẹ lati ṣe iranlọwọ fun awọn ti o fẹ kọ Gẹẹsi ati Yoruba.



You must be logged

Login
5

Bonjour Christophe,


Bienvenu à Lingoid !


Je m’appelle Kevin et je suis philologue en langue française et professeur d’espagnol et d’anglais.


Parlez-vous une autre langue en plus du français ?


You must be logged

Login
8

Hello Christophe! I am glad to hear that you are learning Serbian. :) What do you find the hardest to learn when it comes to Serbian language?


You must be logged

Login